Nigeria Early Grade Reading Assessment: Student Response Form

General Instructions
Oruko mi ni …………………………….. Mo n gbe ni ……………….. mo fe so die fun yin nipa ara mi ( Iye omo ati ojo ori won; ere idaraya ti mo feran ju, eto redio ati mohunmaworan, abbl.)
1. Kin ni o feran lati mase nigba ti o ko basi ni ile-iwe?. Duro fun esi, bi akekeko ko ba fesi, beere ibeere keji, sugbon bi won ba faramo ajose yin, maa ba won soro lo.
2. Awon ere idaraya wo lo wu o lati se ?

Verbal Consent: Read the text in the box clearly to the child.
  • Je kin so idi ti mo fi wa sibi lonii. Ile-ise Eto eko ni mo nba sise, mo si wa lati mo bi eyin akeko se n ko iwe – kika. Ilana oribande la fi yan o fun eto yii.
  • A n fe iranlowo re ninu ise yii, sugbon o le ma ko pa nibe bi ko ba wu o
  • A o se eto iwe-kika fun o bayii. N o wa ni ki o ka awon leta, awon oro ati itan kekere kan to wa ni be soke
  • N o lo aago bere – duro lati mo iye asiko ti o lo lati fi ka won
  • Eto yii ki i se idanwo rara, bee ni ko ni nnkan se pelu ipo re ni ile-iwe.
  • N o tun bi o lawon ibeere nipa ebi re eyi to le jemo ede ti o maa nso nile ati nipa awon nnkan die tie bi re ni.
  • N o ni ko oruko re sile ki enikeni ma ba a mo awon idahun re.
  • Leekan si, bi o ba fe, o le ma kopa ; bi a ba ti bere, o le ma dahun ibeere kankan.
  • Nje o ni awon ibeere kankan? Se o ti setan lati bere?